Lrc Player

Infinity - Aye Ole

Unknown artist
[04:01.11]·
This lyric sheet isn't paired with a song yet, so lines are shown but won't sync or seek.

[00:02.33] Omo eniyan

[00:14.33] F'eti si

[00:16.33] Oro agba, bi o she l'owuro

[00:17.58] A she lowo ale

[00:19.07] Bowun ko pe titi, iya aye wa o n bo wa d'opin

[00:25.83] Aimola eda lo mu eda saniyan ra

[00:34.33] Olorun ti seleri, oro baba ko ni ye

[00:39.58] Aini gbaggbao lo mu eda raropin

[00:44.32] Bi okun n fo

[00:47.08] Ti osa n sa

[00:48.08] Otito wa laaye

[00:50.57] Igbabo ni orisun ohun gbogbo

[00:52.58] Oh hu hu hu

[00:56.83] Aye yi ko male

[01:01.09] Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole

[01:05.82] Oh hu hu hu

[01:08.08] Aye yi ko male o

[01:11.33] Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole

[01:16.58] Hu hu hu

[01:18.57] Aye yi ko male

[01:22.58] Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole

[01:27.57] Oh hu hu hu

[01:30.58] Aye yi ko male o

[01:33.57] Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole

[01:39.08] Oni suuru, ape koto je, koni jebaje

[01:44.08] Ai mani suuru lo n mu are eni bo wa debi

[01:49.83] F'oju re womi ore, k'Oluwa le foju re wo e

[01:55.33] Abiku ti d'abiye ninu aye mi

[02:00.58] Oni suuru, ape koto je, koni jebaje

[02:05.82] Ai mani suuru lo n mu are eni bo wa debi

[02:11.83] F'oju re womi ore, k'Oluwa le foju re wo e

[02:16.83] Abiku ti d'abiye ninu aye mi

[02:21.57] Oh hu hu hu

[02:23.58] Aye yi ko male

[02:27.57] Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole

[02:32.33] Oh hu hu hu

[02:34.82] Aye yi ko male

[02:38.32] Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole

[02:43.32] Hu hu hu

[02:45.08] Aye yi ko male

[02:48.83] Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole

[02:54.32] Hu hu hu

[02:55.83] Aye yi ko male o

[02:59.82] Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole

[03:05.57] Ha ha ha

[03:06.57] Aye re ko ma ni le

[03:10.83] Ha ha ha

[03:12.57] To ba ba Olorun rin, o sho ri re

[03:15.58] Ha ha ha

[03:18.07] Aye re ko ma ni le

[03:21.32] Ha ha ha

[03:23.57] To ba ba Olorun rin, o sho ri re

[03:26.57] Ha ha ha

[03:29.32] Aye re ko ma ni le

[03:32.33] Ha ha ha

[03:34.32] To ba ba Olorun rin, o sho ri re

[03:37.58] Ha ha ha

[03:40.07] Aye re ko ma ni le

[03:43.32] Ha ha ha

[03:45.32] To ba ba Olorun rin, o sho ri re

[03:49.07] Bowun ko pe titi, iya aye wa o n bo wa d'opin